KOOOF continues to turn harvest into hope.

Through the cassava farm of founders, we produced and distributed ‘FUFU’ to widows and elderly women in Ikenne Remo — bringing nourishment, care, and dignity to those who need it most.

To protect their privacy, we use AI-generated images to represent our beneficiaries, but every story behind them is real.

We invite you to be part of this journey. Your support in any form will help us reach more lives, feed more families, and expand this mission of compassion.

Together, we can do more.

KOOOF ń tẹ̀síwájú láti yí ìkórè padà sí ìrètí.

Láti inú oko ẹ́gẹ́ owó olùdásîlẹ̀ wa, a ṣe FUFU tí a sì pín fún àwọn opó àti àwọn ìyá àgbàlagbà ní ìlú Ikenne Remo, láti mú oúnjẹ, ìtọ́jú àti ìyì wá sí ìgbé ayé àwọn tí ó nílò rẹ̀ jùlọ.

Láti bọ́wọ̀ fún ìpamọ́ àti ìyì wọn, a ń lo àwòrán tí ‘AI’ ìgbàlódé ṣàfihàn wọn, ṣùgbọ́n gbogbo nkan ti a kọ dúró fún òtítọ́.

A ń pè yín láti darapọ̀ mọ́ wa nínú ìrìnàjò yìí. Ìtìlẹ́yìn yín — bóyá kékèké tàbí púpọ̀ — yóò ràn wá lọ́wọ́ láti ṣe ìrànlówo fún ọ̀pọ̀ ènìyàn síi, láti fún wọn ni oúnjẹ, àti láti má ṣe ìrànlówo fún òpó àwọn ènìyàn wá ti wọn nílò ìrànlówo.

Àgbájọ ọwọ́ là fi ńsọ́’yá, ọwọ́ kan kò lè gbé ẹrù dé orí. Ẹ jẹ ki a jíjó ṣé ẹyin ará wa.

Category
Tags

No responses yet

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *